ORIN OMON OGUN

 

Eyin o Eje ki won o sun
E jxe ki won la ala pelu , won o man
jxu ki won o lo ara won fun ereepa ati ero lasan lo.
Ejxe ki won o bo ewu ogun kuro lorun ara won,
Ejxe ki won o bi inun ti enikan o biri
Eko fila ogun abi ruke lori tiu won yi o de wo saare omo ogun lo wa
Ejxe ki won o rin
Kaakiri laiman ma mun nkan ijxa danin,
tititiwon o fi ri wipe ko si ogun
Kankan to fe ja man.
E jxowo, ejxe ki won sun,
Titi aaro ile yio fi so won, ti won o si nife si ati pada lo si ile

 

Vertaling: Gbdamassi Latifou

Henk van Zuiden